Adéjọké̩ Ẹwàèdè
@AdejokeEwaede
Yorùbá dùn! I am an African art revitalist, protection&promotion of yorùbá language is my destined assignment.Our cultural heritage mustn’t go into extinction.
Èdè yorùbá ò níí paarun.Just as we have promised,our yorùbá trivia games ll be happening twice a week.Join us again tomorrow as we celebrate the beauty of our culture& language.It promises to be interesting,I am looking forward to having your contributions Yorùbá dùn.

Orí rẹ dára, ìwà rẹ ni ò sunwọ̀n, in most cases, setbacks are not spiritual attacks, but results of your characters. Ẹni ayé n ṣe ò tó nkan, ẹni ìwá takò l'ó pọ̀jù. Ire o!
I know you understand yorùbá, but I am not sureyou know what this DOOR is called in yorùbá. Swipe left to see a clearer pics 😂 #10,000 is here for the first person to answer correctly. Yorùbá dùn, ẹwà púpò̩ n bẹ nínú ède yorùbá🥰


Ká fi ọwó̩ wọe̩ ọwọ́, ká fi ẹsẹ̀ lu ẹsẹ̀, bí èrò bá papò̩, àjò kìí jìn. @bellanaija thank you for the feature, àṣà òun ìṣe yorùbá ò níí paarun o 🙏

Preserving and Promoting the Yoruba Culture in Modern Times dlvr.it/TLx5HB
Ògún dá ọ̀ràn kan, kò ì ran tán... Concentrate your time and energy on doing one thing at a time. Ire o!
Àdìrẹ is SACRED It is not just a fabric. Do your businesses, print as many beautiful designs as you wish, BUT take àdirẹ designs off your machines. Ire o! #adire #originaladire #indigenous #notoprintefadiredesigns
Bí orí bá n fó̩ ajá, ìta gbangba l'à n báa.. Every great MAN has fought a GREATER battle. Ire o!
Welcome to the second half of the year, Àwùjẹ̀ ni ìdàjì orí, ìdòdò ni ìdajì ara, ìdajì t'ó kù nínú ọdún yìí, a ò níí lòó nínú ìnira l'áṣẹ èdùmàrè 🙏
The craft of Àdìrẹ is more than fabric it is my inheritance. I could not stand by and watch it fade into obscurity. Each piece of Àdìrẹ tells a story woven in tradition, dyed in resilience, and passed through the hands of generations. #Adire #PreserveTheCraft #houston
A kìí dò̩bálẹ̀ ká ni iná l'ójú. An internationally humble person humbles himself even before those who should be humbled by his presence. Ire o!